adiitu olodumare€¦ · o di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa...

21

Upload: others

Post on 18-Oct-2020

8 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

Page 1: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki
Page 2: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ADIITU OLODUMARE

Page 3: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ADIITU OLODUMARE PADE IJANGBON LONA

NKAN SE

1a. Se apejuwe eni ti o ni ki Adiitu Eledumare lo be

Ogede wa ni oko.

b. Iru Oloye wo ni eni naa

c. Ki ni oruko Baba ati Iya Adiitu Eledumare

d. “O n ni yi, O n ni yi, On ni yi” ki lo fa oro yii ati wipe

tani oro yii nsapejuwe

2a.Iru awon ejo wo ni Anjonnu Ijongbon ro mon Adiitu

Eledumare lese fun awon igi.

b. Daruko awon oniruru eranko afayafa ti Anjonnu iberu

ko jade ninu apo re.

c. Ki ni Adiitu Olodumare ri ti o fi taji loju orun.

d. Tani o so oro yii ati tani o n so oro naa fun –

“Iroko, iwo ni awon omo enia nla se aga, iwo ni nwon

nla se ibusun, iwo ni nwon nla se apoti, iwo ni nwon tun

Page 4: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

nfi se posi oku won. Ko si nkan ti nwon ko nfi oju re ri.

Wo eleyi, omo enia, o ko oniruru nkan buruku gbogbo, o

n gbe kiri lati ba fi se ibi. Eru buruku na lo wa lori re yi,

nje mo bi o, o ye ki n pa je tabi ko ye? O ye ki n pa eniti

ngbe ejo oka kiri lati fe se ibi tabi ko ye? O ye ki n pa

eniti ngbe paramole kiri fun ijamba tabi ko ye?

e. Ma bo, iwo ti o wa lori igi, ikun re bamba, ehin orun

re bakimo, ibadi re rapata yio se ipade ninu isasun obe

mi

Tani o so oro yii?

Ta si ni oro naa n bawi

3a. Daruko awon oye ti o wa ni Ilu Ifehinti

b. Ki ni o gbehin ekeji Oba ilu Ifehinti

c. Tania won Yoruba n pe ni abobaku ni ile Yoruba

d. Oruko miran wo ni a n pe abobaku ni ile Yoruba.

Page 5: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

4a. Yato si ile Yoruba, orile ede miran wo ni a tun ti le ri

abobaku nigba lailai nile Afirika.

b. Nisisiyi o ti se ase-ma-se, o gbagbe ipo re o si ja sinu

kanga, o si omonikeji re lona, o fi oko oloko fun eni

eleni, Babalawo ilu dajo fun o, Olorise Ilu dajo iku fun

o, Sango ilu dajo iku fun o, Oya ilu dajo iku fun o,

Egungun ilu dajo iku fun o, Oro ilu dajo iku fun o, awon

Oso ati Aje, gbogbo Elebologun patapata, lomode,

lagbalagba, lokunrin, lobinrin ati gbogbo arugbo

porogodo, gbogbo won lo dajo iku fun o. Gegebi ofin wa,

ekeji ilu, ki ori re to kuro lorun re, wi fun ni, tani ki o ku

pelu re?

Tani o so eleyii?

Tani won so sii?

Page 6: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ALABAPADE ADIITU OLODUMARE

1a. Ni ojo ti mo ti nri ehin ti o funfun, nko ri ehin ti o

funfun bi ti okunrin naa ri, ni ojo ti mo ti nri ahon, nkori

eyiti o pon dede bi enipe onje ko da a ri bi tire, ni ojo ti

mo ti n ri oju ti o mole gara, nko ba iru ti okunrin yii

pade ri. Ki a si so pe enia soro o fi oro wu enileyi so,

enia rin lese, o fi irin wu elomiran rin, enia wo aso, o mu

ki a ma wo aso naa kiri, tabi iho ninu eni mo, tabi apa

eni ko gun lasan jawala, tabi omo ika owo ba owo mu,

omo ika ese ba ese mu, ti okunrin naa yato lopolopo.

Tani eniti n soro yii n sapejuwe?

2a. Igba ti ojo naa sip o pupo to bayii, dereba ko ri ibi

iwaju mo, asehinwa asehinbo dereba fa kokoro yo loju

moto, o gbe ese le ibi idaduro oko, oko duro gbonin, o di

ki a ma wa wo oju ara wa. Bi o si tile je pe ati gbogbo

ilekun mo ara wa lori pinpin, ti enikeni ko gbin, ti enia

ko soro, sibe okunrin kan lu moto le wa lori. Okan ilekun

lekini, o kan a lekeeji, o tun kan a lekeeta, a ba silekun a

wo ode”

Page 7: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

Tani o n lu moto?

Ki ni oun lu moto si fun

Page 8: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

OBIRI AYE ATI IPONJUDIRAN

1a. Ki enia ji, ki kobo se alai ba a ji, ki enia ko aso si ara

ki o dabi jowolo ogede fun akisa, ki odidi ile ojo kan su

lai bu omi si enu, ki enia di eniti o nti epo isu ti a fi gun

iyan je, ki enia bo si ori atan ki o ma wa epo buredi, ki

elewa je ewa tan ki a ma fi nkan ha redi ikoko ewa, ki o

di pe Oloye n wa onke a ti itori be lo le gongo sile

olonje, ki okunrin ni woro ibante kan gege bi aso, ki

obinrin ma ni ju yeri

Kini Olusoro nsapejuwe?

b. Durko oruko ilu Baba ati iya Adiitu Olodumare

c. So eredi ti awon ebi Adiitu Olodumare fi talaka to be

d. Se apejuwe eranko ti a n pe ni Ilakose?

e. Ki ni iyato ti o wa laarin igbin ati ilakose

2a. Ise wo ni awon ara ilu ilakose nse

b. Fi ami si ori awon oro wonyii:

Page 9: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

i. Ilakose

ii. Gongosu

iii. Alainironu

iv. Bamubamu

v. Alaimero

vi. Obo Lagido

c. Tani o n kigbe bayii

E:- e:- e:- e- E- e- e- E jowo e gba mi o – o – o ! Gbogbo

ara aiye, egba mi, gbogbo ero orun, egba mi, gbogbo

anjonnu aiye, egba mi, gbogbo sigidi adahunse, e gba

mi, sango, jowo gba mi, Jesu onigbagbo, Obatala jowo

gbami, Anabi onimale, gba mi, Edumare, temi dowo re,

gbogbo omo ilakose, agbe ilakose, onisowo ilakose, eni

keni ni ilakose, e jowo e gba mio:-:-:-:-:-:-o”

Page 10: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ADIITU OLODUMARE DI ERO INU IGBO

1a. Baba mi, mo dupe lopolopo fun bibi ti e bi mi. Lai se

ainiaini, bi o ba je bayi ni e wa tele, e ko ba ti ni ero pe

ki e bi mi, e ko ba tile le to eniti nni obinrin. Sugbon

ayipada ti de. O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje

mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi

bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki n fi

ori le ibikibi ti mo ba ri, boya bi emi ba lo, enyin ati iya

mi le ri ona ati ma toju ara yin, a je pe ng o ri yin,

sugbon bi eleda ba pe oni ni arimo, a o ma pade ni ode

orun.

Tani o soro yii

Tani oro naa n bawi

Kini esi ti eniti o n baa wi fo

b. Ko lessee ohun ti o sele si Adiitu Olodumare ni ojo

meta lehin ti o gbera kuro nile

c. Bawo ni Adiitu Olodumare se pa ejo buburu naa

d. Odun meelo ni Adiitu Olodumare gbe ninu Igbo

Page 11: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

e. Kini iyato ti o wa laarin eniyan ati obo

2a. Ha! Eleda mi, temi ti je?

Olodumare, temi ti je?

Temi ti je laarin omo enia?

Baba mi wa onje, ko ri je

Iya mi wa onje ko ri je

Mo t’ori bo ‘gbo nitori ati je

Mo di egbe akata tori ati je

Alabagbe kiniun, tori ati je

Ekeji Imado tori ati je

Ona kona tin g o ba gba loni,

Iwo eleda mi, ma sai ko mi

i. Nje a le pea won oro oke yii lewi bi

ii. Tani o so oro yii

Page 12: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

iii. Kini o sele ti o fi so awon oro wonyii.

b. Fi ami si ori awon oro wonyii

i. Teletele

ii. Sobolo

iii. Bamubamu

iv. Apoluku

v. Jowolo

vi. Ajedubule

vii. Edegbewa

viii. Akosile

ix. Obiri Aiye

x. Adiitu

c. Kini oruko omo itunu-aye aiyedemi

d. Awon nkan Ogun wo ni won pin kan lehin iku baba re

Page 13: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

e. Awon nkan Ogun wo ni won pin kan Ireke Onibudo

funra ara re

2a. Se apejuwe iyato ti o wa laarin awon aso wonyii –

etu, alari, adire, aso elepa, sanyan, aso oke, damaasi,

aran.

b. Daruko awon nkan ti Adiitu Olodumare ra lo fun Iya

re

c. Iru iku wo ni o pa awon obi Adiitu Olodumare

d. Awon ohun wo ni Adiitu Olodumare se ni iranti awon

obi re

e. Awon ise ilu wo ni o tun se pelu.

Page 14: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ADIITU OLODUMARE LA ALA IYANU

1a. Ni soki se akosile ohun ti Adiitu Olodumare ri ni oju

orun

b. Ki ni ise angeli itoju emi?

c. Kini awon eran ohun osin ti won n wo tele ara won fe

lo se

d. Daruko awon eranko osin ohun

e. Ise wo ni digi n se ninu ala naa

2a. Iru ile wo ni ile Ope je

b. Iru awon eniyan wo lo n wo ibe

c. Salaye lekunrere itumo ati nkan ti awon wonyii duro

fun

i. Ako-okuta orun

ii. Akuko Orun

iii.Ogunlogo Apoti

Page 15: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

d. Se apejuwe bi Akuko orun se ri

e. Ni soki, so ohun ti o sele laarin Adiitu Olodumare ati

Obiri-aiye

Page 16: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

ADIITU NFE IYUNADE

1a. Bawo ni Ademe to se je si Adiity Olodumare

b. Kini a n pe ni Iyun ni ile Yoruba

c. Ise wo lo n se

d. Bawo ni Iyunade se je si Ademeto

e. Tani oro yii n se apejuwe –

“O dara lomobinrin, egan lo ku. O pupa roboto, gbogbo

ara ri minijo, ko sanra bakiti lasan, beni ko ru han-gogo,

o ri sosoro o sig a die, gbogbo nkan ti obinrin fi iwu ni ni

o ni gbogbo, eyinloju mole kedere, ko pupa rakorako bi

oju ejo. Bi enia ba wo ipenpeju re o dabi eni pe

Olodumare da tire se loto, ti o to nkan dudu tere sii, ete

ko fele rekoja, beni ko nipon pon-on-pon, ehin funfun bi

ojo ojo, ese ko ri tere bi ese oga, beni ko ri jakiti bi ti

ajanaku, ori ko ri gidigbi, kori palaba, kori gboro, eleda

se e ni iwon tunwonsi, o ba orun mu.

d. Kini esi leta akoko ti Iyunade kosi Adiitu

e. Daruko awon nkan ti Adiitu fi ranse si Iyunade

Page 17: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

2a. Bi o ba fe fun mi ni nkan gege bi ore egbon mi, mo

gbo, bi o ba se mi ni alejo ti ko ni igberaga ninu, mo

gba, ki a wipe agolo atike kan pere lo ra wa fun mi, o ba

ri I bi o ti ma niyi to lowo mi, se ni mba gbe o soke ke-

nke.

Inu leta tani eyi ti je jade?

b. Kini o sele ti Iyunade fi n fi Adiitu Olodumare se yeye

c. Fi ami si ori awon oro yii

i. Gombu

ii. Yereku

iii. Ikoko

iv. Iyunade

v. Onibuore

vi. Onimale

d. Kini iyato ti o wa laarin omo buroka ati ipata omo

e. Kini o fa ti ara Iyunade ko fi ya

Page 18: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

3a. Tani o so oro yii

Egbon mi, nko le be Adiitu rara, e jowo e je kin lo ola ti

Olodumare fun mi gegebi Obinrin. Lona kini Adiitu kii

se oko mi, ki itile se oko afesona rara, ki a wipe a fe ara

wa nijomiran ni mo le bee, sugbon eyi ni papa ko le bo

sii.

b. ki lo de ti Iyunade pe Adiitu ni Ogonju Orun

c. Tani esu-lehin ibeji

d. Kini o de ti esu lehin ibeji fe fi pa Adiitu

e. Tani esu lehin ibeji pa dipo Adiitu Olodumare

Page 19: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

EHIN IGBEYAWO ADIITU OLODUMARE

1a. Tani Enudunjuyo

b. Tani o so oro yii

“Gbogbo eyin omo Ajedubule, mo ki yin, gbogbo alejo

Ajedubule, mo ki yin, mo ki onile, mo ki alejo, mo ki oso,

mo ki aje, mo ki babalawo, mo ki adahunse, mo ki olowo,

mo ki talaka, mo ki eniti o rije, mo ki eyiti ko rije ,

gbogbo enyin igbagbo, mo ki yin, gbogbo enyin imale,

mo ki yin, gbogbo enyin aborisa mo ki gbogbo yin

porogodo.

c. Tani Oba Okonko

d. Kini Olori Esan-mbo se ti won fi ti mon inu iboji

e. Iru eniyan wo ni Alabapade je?

2a. Tani o gba ero lati pa Esan-mbo

b. Kini esi ti Esan mbo fun alabapade

c. Tani o n je omo owu

Page 20: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

d. Ki ni alabapade ri lara esan-mbo nigba ti o fe sunmo

e. Tani o ko sibe

3a. Enu awon wo ni Oba ti gbo wipe Esan-mbo ko ku

b. Kini ase ti Oba Okonko pa fun awon onise re pe ki

won se fun Esa-mbo ati alabapade

c. Iru iya wo ni Oba Okonko fi je Esan-mbo

Page 21: ADIITU OLODUMARE€¦ · O di owuro ana ti mo ti fie nu mi ba onje mo, sugbon nko ri ki enyin papa jeun, nko siri ki Iya mi bu okele. Nitorina, mo fe lati jade kuro ni arin ilu, ki

OJO KEJI NINU ILE MOGAJI ENUDUNJUYO

1a. Daruko awon eko ti a riko ninu itan Enudunjuyo

b. Iru eniyan wo ni Kotemilorun je

c. Ki ni oruko ore re

d. Iru awon Ibeere wo ni Esu Elegbara n bi awon ti won

wa si ipade

e. ki ni oruko ore Kotemilorun ti o bere lowo re wipe se

enia tun le lo si ibikan lehin iku?