ÌtỌ́nisÓṆÀ jòẉó ̣kóḳó ̣kà Á · fun ní ìwé nítorí ohun pàjáwìrì tó...

13
ÌTỌ́NISỌ́NÀ Jò ̣wó ̣ Kó ̣kó ̣ Kà Á 1. Kọ́kọ́ parí fífi ìròyìn sílè ̣ lórí fọ́ọ̀mù Ìfikún. Kì í e dandan kí o dáhùn gbogbo àwn ìbéèrè. Bó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ó e kókó kí o falà sí (àwn) àpótí tí yóò àlàyé dáadáa fún Ilé jọ́ ìdí tí o fẹ́ fi pínyà. Èyí yóò ti Ìbéèrè fún Ìpínyà r àti àwn Ìbéèrè fún ìdádúró fún ni fún ìdáàbòbò pàjáwìrì lé ̣yìn, tàbí láti dá Ilé jọ́ dúró láti fún láti ni tí a pè lẹ́jọ́ dúró láti kàn sí . 2. Tó bá ku díẹ̀ káàtó fún , jọ̀wọ́ ri pé o párí Fọ́ọ̀mù tó y (O.8, R.1). Àwn ẹ̀dà òfìfo wà nínú ìdì fọ́ọ̀mù yìí. 3. ẹ̀dà, kí o sì fi èdìdí stanpu méjì (ọ̀kan fún 'Ilé jọ́ bí' èkejì fún 'Ojúlówó Ẹ̀dà') si, kí o sì tọ́jú fọ́ọ̀mù tí o ti parí, tí wọ́n ti bu wọ́ sí pẹ̀lú déètì fún àkọ́lẹ̀ ara r. Wà á tún ní láti fún lọ́pàá ní è ̣dà gbogbo fọ́ọ̀mù tí o ti parí, kó ba lè fún ni tí a pè lé ̣jọ́ ní àwn ìwé wọ̀nyí. Bákan náà kí o sì so À èyíkèyí, bí i À Tí Kò Fàyè Gba Ìkánsí tàbí À Pàjáwìrì tí o bá gbà ní Ilé jọ́ lẹ́yìn ìgbẹ́jọ́ r mọ́ . 4. O gbọ́dọ̀ kó gbogbo àwn ojúlówó ẹ̀dà àksílẹ̀ r l sí kùn Ilé jọ́ fún agbègbè r tó bójútó abúlé tàbí ìlú tí o wà. 5. Ju gbogbo rẹ̀ l tí owó tí ò gbà kò bá fi ẹ́ hàn gẹ́gẹ́ bí "ni tó kù díẹ̀ káàtó fún", a lè ní kí o san owó fún jọ́ tí o mú wá fún Ìbéèrè ìdúró fún ni. Akò ̣wé ilé jó ̣ yóò s oye tí o máa san ní kété tí o bá ti fún wn ní fọ́ọ̀mù wọ́ r. 6. Tí a bá k (àwn) Ìbéèrè fún ìdúró fún ni r fún ààbò, o lè tún bèrè fún jó ̣ -- té ̣milọ́rùn. A ó sì pèsè fọ́ọ̀mù jọ́ --té ̣miló ̣rùn fún Ilé jó ̣ pè ̣lú fó ̣ò ̣mù Ìfi Lé ̣ta Jíé ̣ . O lè fé ̣ bèrè lọ́wọ́ ilé jọ́ ìgbà tí àkókò fún jọ́ --tè ̣milọ́rùn r yóò tàn, èyí sì lè má pé ̣ púpọ̀ rárá, má e da dúró rárá, ri dájú pé gbogbo fọ́ọ̀mù tí o máa nílò fún ìlànà yìí lo fi sílẹ̀ kó má bà á dènà r tó bá yá.

Upload: others

Post on 20-Mar-2020

15 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

ÌTÓNISÓNÀ

Jòwó Kókó Kà Á

1. Kókó parí fífi ìròyìn sílè lórí fóòmù Ìfikún. Kì í se dandan kí o dáhùn gbogbo

àwon ìbéèrè. Bó tilè jé wí pé ó se kókó kí o falà sí (àwon) àpótí tí yóò sàlàyé dáadáa

fún Ilé Ejó ìdí tí o fé fi pínyà. Èyí yóò ti Ìbéèrè fún Ìpínyà re àti àwon Ìbéèrè fún

ìdádúró fún ni fún ìdáàbòbò pàjáwìrì léyìn, tàbí láti dá Ilé Ejó dúró láti fún e láse láti

dá eni tí a pè léjó dúró láti kàn sí e.

2. Tó bá ku díè káàtó fún e, jòwó ri pé o párí Fóòmù tó ye (O.8, R.1). Àwon èdà

òfìfo wà nínú ìdì fóòmù yìí.

3. Sèdà, kí o sì fi èdìdí stanpu méjì (òkan fún 'Ilé Ejó Ebí' èkejì fún 'Ojúlówó Èdà') si,

kí o sì tójú fóòmù tí o ti parí, tí wón ti bu owó sí pèlú déètì fún àkoólè ara re. Wà á tún

ní láti fún olópàá ní èdà gbogbo fóòmù tí o ti parí, kó ba lè fún eni tí a pè léjó ní àwon

ìwé wònyí. Bákan náà kí o sì so Àse èyíkèyí, bí i Àse Tí Kò Fàyè Gba Ìkánsí tàbí Àse

Pàjáwìrì tí o bá gbà ní Ilé Ejó léyìn ìgbéjó re mó o.

4. O gbódò kó gbogbo àwon ojúlówó èdà àkosílè re lo sí Ekùn Ilé Ejó fún

agbègbè re tó n bójútó abúlé tàbí ìlú tí o wà.

5. Ju gbogbo rè lo tí owó tí ò n gbà kò bá fi é hàn gégé bí "Eni tó kù díè káàtó

fún", a lè ní kí o san owó fún Ejó tí o mú wá fún Ìbéèrè ìdúró fún ni. Akòwé ilé ejó

yóò so oye tí o máa san ní kété tí o bá ti n fún won ní fóòmù owó re.

6. Tí a bá ko (àwon) Ìbéèrè fún ìdúró fún ni re fún ààbò, o lè tún bèrè fún ejó-kò-

témilórùn. A ó sì pèsè fóòmù Ejó-Kò-témilórùn fún Ilé Ejó pèlú fóòmù Ìfi Léta Jísé. O

lè fé bèrè lówó ilé ejó ìgbà tí àkókò fún ejó-kò-tèmilórùn re yóò tàn, èyí sì lè má pé

púpò rárá, má se da dúró rárá, ri dájú pé gbogbo fóòmù tí o máa nílò fún ìlànà yìí lo fi

sílè kó má bà á dènà re tó bá yá.

Kí ni ÀSE ÌBÉÈRÈ FÚN ÌDÁÀBÒBÒ PÀJÁWÌRÌ ÌDÚRÓ FÚN NI?

Ìdúró fún ni túmò sí kí Eni tí a pè léjó tàbí agbejórò rè má sí ní ilé nígbà ìgbéjó, tàbí kí á

fun ní ìwé nítorí ohun pàjáwìrì tó selè lórí èsùn tó wà nílè.

Pàjáwìrì túmò sí ohun tó n sè lówólówó.

Àse Ìdáàbòbò túmò sí pe a dá ààbò bo olùfisùn lówó eni tí a pè léjó.

Àse Ilé Ejó jé àwon àtúnse tí Ilé Ejó sèdá, níbi tí olùfisùn kò bèrè fún owó fún àdánù

rè, sùgbón ó n bèrè fún àtúnse tí yóò dékun ohun kan tàbí òmíràn láti wáyé.

Ohun Tí Kò Kàn Wá:

Tí o bá fé dúró fún ara re láti bèrè ìgbéjó ní Ekùn Ilé Ejó ní Cyprus fún Àse Ìdáàbòbò Pàjáwìrì

Ìdúró fún ni láti lè dá (àwon) eni tí a pè léjó dúró, kí wón má bà á kàn sí e. A pèsè àwon

fóòmù àti ìtónisónà wònyí gégé bí ìtóni fún e láti lè fi ran ara re lówó. Kí wón má sì lò ó gégé

bí ìmòràn fún òfin tàbi kí o ri gégé bí ohun tó sojú ètò òfin.

Ní Ekùn Ilé Ejó Ebí ti................... ⃝ Nicosia ⃝ Limassol ⃝ Larnaca

⃝ Famagusta ⃝ Kerynia ⃝ Paphos

.................... ní 20…

Láàrin .......................A.B, .................... Olùfisùn,

Àti

............................C.D, ........................ Eni tí a pè léjó.

I. Ìbéèrè Fún Ìpínyà:

Irúfé Ìgbéyàwó: ⃝ Tó Jemó Òfin ⃝ Èsìn (Létà Ilé Ìjo - wò ó, a sómo)

Α) Ó jé ìdájó Ilé Ejó láti fi òpin sí ìgbéyàwó àwon tí ìgbéyàwó won wáyé ní ...........

ní Ilé Ìjo ti..................................., tàbí ní Gbògán níbi tí ti fi owó si tí wón sì gbà á

wolé, pèlú nónbà ____________________ (wò ó a sómo) nítorí àwon okùnfà tí eni tó

mú ejó náà so nísàlè:

Àwon Okùnfà:

Àjosepò Tó Ti Bàjé Kojá Àtúnse – Ìjà Tí Kò Seé Là ⃝

Panságà ⃝

Ìsesí Tí Kò Sí Àwáwí Fún ⃝

Ìyànjú láti pa enìkejì ⃝

Wèrè Síse ⃝

Eni tí a Dájó Èwòn Fún ⃝

Ohun tó Farasin ⃝

Àìlerà ⃝

Ìgbàgbé Enìkejì Láìnídìí ⃝

Àyípadà Èsìn ⃝

Ìfé Inú Eni Fún Omo Bíbí ⃝

Àwon Ìdí Mìíràn: ⃝

Àlàyé Lórí Ìpínyà Nílò Ìtójú:

A. Ìpínyà Wón Jiyàn ⃝ Won Kò Jiyàn ⃝

B. Pèlú Omo ⃝ (Wò ó níbi tí a soó mó) Láìsí Omo ⃝

C. Pèlú Ohun-ìní ⃝ (Wò ó níbi tí a soó mó) Láìsí Ohun-ìní ⃝

Ìròyìn Nípa Àwon tí Òrò Kàn:

Olùfisùn:

Orúko:

Orúko Ìdílé:

Fóònù

Ojó Ìbí Eni

Àdírèsì Àdúgbò/Ìlú:

Kóòdù Ìfilétà Ránsé

Osù tàbí Odún Níbi

tí Ò n Gbé Báyìí,

Ilé

Eni tí a pè léjó:

Orúko:

Orúko Ìdílé:

Fóònù

Ojó Ìbí Eni

Àdírèsì Àdúgbò/Ìlú:

Kóòdù Ìfilétà Ránsé

Osù tàbí Odún Níbi

tí Ò n Gbé Báyìí,

Ilé

II. Ìbéèrè fún ÀtìléyìnToko-tayà:

Wón Jiyàn ⃝ Won Kò Jiyàn ⃝ (Wo Àdéhùn Tí A Somo)

Α) Àse Ilé Ejó tó pàse fún Eni tí a fi èsùn kàn wí pé kó san owó tí iye rè jé €

..................... .. gégé bí owó ìtanràn ìpínyà fún eni tó mú ejó wá ní kété tó bá ti fi

orúko sílè tán gégé bí owó ìtanràn àti owó tí yóò máa fi tójú àwon omo kékéèké tó wà

nílè. Ilé Ejó ni yóò so oye tí yóò máa sàn léyìn tí wón bá tí gbe yèwò, tí wón sì mo

ohun tó tó, tó sì ye.

B) Àtúnse mìíràn tí Ilé Ejó bá rí gégé bí ohun tó tó, tó sì ye lórí ohun tó wà nílè.

C) Iye tí wón ná lórí ìbéèrè fún náà (pèlú Owó Orí Aláfikún) àti oye tí won yóò gbé

létà náà.

D) Ohun-ìní àti Ohun tí Wón ti Ná (Wo Ìwé Ìsuná tí a so mo Láti Fìdí Rè Múlè)

E). Ìbéèrè fún Kí Wón Gbésè Lé Ohun-ìní: Béèni ⃝ (wo ohun tí a so mo) Béèkó ⃝

III. Ìbéèrè Fún Àse Ìdádúró: …… ìdúró fún ni ⃝ (wo ohun tí a so mo) Ìbéèrè fún

Ìgbéjó ⃝

Ìbéèrè fún ìfibú pé àwon omo kekeeke tó wà láàrin àwon tí òrò kàn kò gbódò rin

ìrìnàjò kúrò ní Cyprus:

A . Àse láti Ilé Ejó tó fibú wí pé àwon omo kekeeke àwon tí òrò kàn

.................... kò gbódò jáde kúrò ní Cyprus láì jé pé wón gba ìwé ìfowósí eni tó mú

ejó wá láti se béè tàbí láìsí àse láti Ilé Ejó

B . Kí àse tó máa ní orúko àwon omo kekeeke àwon tí òrò kan

............................ wà nínú àtòjo àwon tí a ti fi òté lé lórí láti rin ìrìnàjò jáde nínú

Cyprus.

C. Àtúnse mìíràn tí Ilé Ejó bá rí gégé bí ohun tó tó, tó sì ye lórí ohun tó

wà nílè.

D. Iye owó tí wón ná lórí ìbéèrè fún

IV. Ìbéèrè Fún Àse Ìdáàbòbò: Béèni ⃝ (wo ohun tí a so mo)

ìdúró fún ni ⃝ wo ohun tí a so mo) Ìgbéjó ⃝

V. Ibi tí Omo Máa Wà

Wón Jiyàn ⃝ Won Kò Jiyàn ⃝ (Wo Àdéhùn tí A Somo)

Α) Àse Ilé Ejó tó fàyè gba Eni tó Béèrè Fún Nnkan láti jé kí omo náà kó wà pèlú rè

Β) Béèrè fún Ìkéde Ilé Ejó láti fún Eni tó Mú Ejó wa láàyè láti má pèsè ìpamó, ìtójú

àti ìbójútó fún omo kekeeke náà.

C) Àse tàbí ìtójú mìíràn tí Ilé Ejó bá rí gégé bí ohun tó tó, tó sì ye lórí ohun tó wà

nílè.

D) Iye owó tí Wón Ná (pèlú Owó Orí Aláfikún) (Wo ohun tí a somo)

A fi lélè ní .......................... ojó....................... ni

_________________________________________________

Olùfisùn

(A ti Fowósi)

Akòwé Àgbà Ilé Ejó.

ÌBÚRA

Èmi,…………………………………………………………………………………

láti ………………………………………………………… tó jé eni tó ní Òrò-

àsírí/Káàdì Àlejò/Káàdì Ìdánimò pèlú Nónbà.……………………………….....

Mo se ìbúra àti wí pé àwon nnkan wònyí tí n ó so jé òtító, béè sì ni wón tònà dé ibi tí

ìmò mí dé lórí won:

Wo ohun tí a somo:

⃝ Ìbéèrè Fún Tí a ti Jérìí fún Ìpínyà

⃝ Àkoólè Ìsúná Owó àti àwon àkosílè mìíràn tó jo ó tí a ti Jérìí Rè

⃝ Ìbéèrè Fún Eni Tó Kù Díè Káàátó Fún

⃝ Ìbéèrè Fún, fún Àse Ìdáàbòbò Láìsí Ni Níbè fun Ara Eni ____ Àwon Omo _____

⃝ Ìbéèrè Fún Àse Ìdádúró ni Láìsí Ni Níbè

ENI TÍ A BÚRA FÚN NÁÀ

………..………..………….……………

Wón búra, Wón sì tí fowósí i níwájú mi

sí Ekùn ilé ejó ti ……………………..

lónìí …………………………………..

AKÒWÉ ÀGBÀ ILÉ EJÓ

ÀKÓSILÈ ÌWÉ ÈTÒ ÌSÚNÁ OLÙFISÙN TÍ A JÉRÌÍ SÍ

I. Àkósilè Ìwé Ètò Ìsúná

1. Ohun-ìní: Gbésèlé ⃝ Ìgbéjó ⃝

A. Ilé: Iye Tó Jé : ___________

Ilé Ibi Tí À N Gbé Tí Iyànjíjà Wà Lórí Rè ⃝

Àwon Ilé àti Ilè Mìíràn

Àdírèsì:

__________________________________________________________________

__________________________________________________________________

B. Àkoólè Owó Nílé Ìfowópamó:

1.

2.

3.

C. Ìsura Ojà:

1.

2.

3.

D. Ìwé Àdéhùn Láti Sanwó:

1.

2.

3.

E. Àkójopò Owó Ìfèyìntì:

1.

2.

F. Àkójopó Owó Mìíràn:

1.

2.

G. Ohun-ìní Àdámó Eni

1. Ohun Òsó Ara:

2. Ohun Onà:

3. Ohun-èlò Ilé:

4. Nnkan Ìgbàanì:

5. hun-ìní Tí A Jogun:

6. Àwon Ohun ìní Mìíràn tó Je Ti Eni:

2. Owó Tó N Wolé

Olùfisùn:

A. Owó Isé Osoosù:

B. Owó Isé Ara Eni Osoosù:

C. Owó Míràn Tó N Wolé/Gbogbo Ònà Mìíràn Tówó N Gbà Wolé:

D. Èrè Gbogbo:

E. Owo Odoodún:

F. È rè Lórí Isé Tí A Fowó Sí:

G. Àwon Orísun Mìíràn Tówó N Gbà Wolé/Àpapò Owó Gbogbo Tó n Wolé:

3. Ìsúná Owó Osoosù

1. Owó Sísan Lórí Ilé Tí A Rà:_________

2. Ohun-èlò gbogbo:__________

⃝ OMI ⃝ INÁ OBA

3. Oúnje:_________

4. Aso Wíwò: Fún Ara Eni ⃝ Fún Àwon Omo ⃝

5. Ogún:_________

6. Èkó:_________

7. Fóònù:__________

8. Owó Ìrìnkèrindò Okò:___________

9. Owó tí a Yá

10. Owó mìíràn tí a Yá

9. Àwon Ìdí Mìíràn:

_____________________________________________________________________

_____________________________________________________________________

_____________________________________________________________________

3. Owó Ìtanràn tí Oko N San Fún Ìpínyà: Omo Méta àti eyokan ⃝

a. Tí Eni Tó Mú Ejó Wá Bá Jé Aláàbò ara ⃝

b. Tí Àwon Omo Eni Tó Mú Ejó Wá Bá Jé Aláàbò Ara ⃝

4. Ìròyìn Nípa Ibi Tí Omo Wà àti Àtìléyìn Rè

Àwon Omo Kekeere: Iye won_________

Sàtòjo (Àwon) Ojó Orí Àwon Omo

_____________________________________________________________________

_____________________________________________________________________

Àwon Omo Tó Ti Dàgbà, tí wón wà ní Ilé Èkó – Ojó Orí Won Ju

Méjìdínlógún lo:__________

5. Ibi Tí A Tójú Àwon Omo Sí: Àdéhùn (wo ibi tí a somo)

⃝ Kò sí àdéhùn

⃝ Ìgbéjó Máa Nílò Ibi Ìtójú Àwon Omo / Tàbí Ohun Tí A

fé Se Nípa Rè

6. Ìbéèrè Fún Àse Láti Dá Nnkan Dúró

Ìdí: ⃝ Toko-taya Tó Jé Àjòjì / Èrù Kí Wón Má Jí Ni Gbé ⃝ Ìwà ipá

⃝ Kò Sí Àyè fún Ìwà Ipá, Kò sí Àyè Fún Enikéni Láti Fi Owó Kan

Elòmíràn

⃝ Àwon Mìíràn

____________________________________________________________

A Fi ejó yìí lólè ní.......................... ojó....................... ní ……………….

_________________________________________________

Olùfisùn

(Tí a fowósí)

Akòwé Àgbà Ilé Ejó.

FÓÒMÙ ÀKÓKÓ.

ÌWÉ ÒFIN FÚN ÌPÈLÉJÓ (O. 2, R. 1)

Ní Ilé Ejó Ebí ti................... Nonba....................ti 20…

Láàrin

Olùfisùn

Àti

Eni tí a pè léjó

Sí C.D. ti

(a)...................................(b)...........................

Èyí ni láti pa àse fún e wí pé láàrin ojó méwàá léyìn ìpèléjó ìwé òfin yìí, o ti wo ìpeniléjó pèlú

A.B ti

(a).......................................(c)................................

A ó fi ìbéèrè fún Olùfisùn séyìn ìwé tí a fowósí.

Àdírésì Olùfisùn fún ìpèsè isé jé (d).................................

Kí o sì kíyèsí pé, tí o ba ko lati farahan ni ona ti a so si isale yii, Olùfisùn le tesiwaju, won yóò

sì se ìdájó láìsí e níbè.

A fi lélè ní.......................... ojó....................... ní ….

(A ti fowósi)

Akòwé Àgbà Ilé Ejó. (Ìfowósí)

Agbejórò fún olùfisùn

ÀKÍYÈSÍ —Ìfarahàn lè wáyé nípa pé kí olùfisùn fúnra rè wá tàbí kí agbejórò rè wá sódò

Akòwé Àgbà Ilé Ejó ní (f) ............ Kí wón se ìwé ìránilétí pé ó wá, láti fí jérìí àdírèsì

Olùfisùn, kí wón sì fi déètì si lójó náà, kí ó lè wà gégé bí èdà fún ojó mìíràn, kí Akòwé Àgbà

Ilé Ejó sì fowósi pèlú èdìdí.

_____________________________________

(a) Ko àdírèsì ní kíkún kí o so orúko àdúgbò àti nónbà ilé náà tó ba ní. (b) So isé tí Eni tí a pè léjó n se tí o bá mò ó. (c) So isé tí Olùfisùn n se. (d) Fún won ní orúko kikun, ise ati adiresi eni tó n gbé ní agbègbè tó súnmó ìlú tàbí abúlé ibi tí nnkan tí ìsèlè náà, tí a lè fún ní àkosílè tí a fé fún Olùfisùn náà ní kíkún. (e) Akòwé Àgbà Ilé Ejó ní kó ko déètì náà. (f) Dárúko ìlú tàbí abúlé tí ibi ìforúkosílè tí a sàpèjúwe lókè yìí wà (d). KÍYÈSÍ —Tí o bá fé sàgbékalè ìwé òfin, ká kíyèsí láti wo ohun tí Àse Kejí tí a pèsè àti àwon àse tó n darí ìfowósí so. Àkíyèsí fún Eni tí a pè léjó— Eni tí a pè léjó tó fé gba agbejórò, gbódò fi sókàn wí pé, àyàfi tí adájó bá lo kúrò agbejórò kò lè dúró fun, àfi tí a bá ti fun ní àse nínú ìwé tí a ko nínú Fóòmù 12A, tí Eni tí a pè léjó sì ti Fowósí.

Ìfowósí Ètó

Ètó Olùfisùn jé:

Ojúlówó Èdà

Akòwé Àgbà Ilé Ejó

(a) Agbejórò fún Olùfisùn

__________________________________________

(a) Fagilé "Agbejórò" tó bá jé wí pé ìwo fúnra re lò n fi ejó sùn.

Ìbéèrè Fún Ìgbèjó Eni Tó Kù Díè Káàtó Fún (O.8, R.1)

Ní Ekùn Ilé Ejó tí ……………….. Nonba

_________________Olùfisùn

ÀTI

_________________ Eni tí a pè

léjó

Oníbèérè ti bèrè fún ìdúró fún ni láti lè fi ní

déètì ìtura ìgbéjó lori________________. (deeti)

Eni tó mú ejó wa náà máa so wí pé òun náà wá gégé bí eni tó kù díè káàtó fún nítorí

àwon ìdí tó wà lábé Àse kejo, Òfin kìíní tí Òfin Ìlànà Ajemó Òfin Ìlú:

(i) wí pé òun kò ní tó €171 (yàtò sí aso tó n wò, ibùsùn àti òrò tó mú wá

sílé ejó);

(ii) wí pé gbogbo owó tó n wolé fún òun kó kojá €9 lósóòsè; àti

(iii) wí pé ohun ní ìdí tó ye láti pé onítòhún léjó tàbí láti dáhùn ejó.

Eni tó mú ejó náà wa, máa fi Ìbura sílè láti fi ti àwon gbólóhùn òkè wònyí léyìn fún

ìbéèrè fún re.

Orùko:

A fi lélè ní ____________ Ìfowósí:

AKÒWÉ ÀGBÀ ILÉ EJÓ