leta ife lati odo olorun baba - the lord loves you · 2010-04-09 · leta ife lati odo olorun baba...

1
Leta Ife Lati Odo Olorun Baba Iwo, Omo mi owon,… O le ma mo mi; sugbon, mo mo ohun gbogbo nipa re …Orin Dafidi 139:1 Emi mo gbogbo bi o se njoko ti o si ndide … Orin Dafidi 139:2 Ko si ohun kan nipa re ti o s’okunkun si mi Orin Dafidi 139:3 Emi mo iye irun ti o wa l’ori re …Matteu 10:29-31 Ni aworan ara mi ni a da o …Genesisi 1:27 Ninu mi ni o ngbe, ni o nrin, ti o si nni iye …Ise Awon Aposteli 17:28 Lati inu mi ni o ti jade wa …Ise Awon Apostei 17:28 Ki a to bi o ni mo ti mo o…Jeremiah 1:4-5 Mo ti yan o ni ayo ki nto da ohun gbogbo…Efesu 1:11-12 Igbesi aye re ko le je asise; nitori wipe mo ti ko won si inu iwe mi …Orin Dafidi 139:15-16 Emi ni mo se ipinnu asiko gere eyi ti a bi o ati ibiti o ma a ma gbe …Ise Awon Aposteli 17:26 Iyanu gan ni eda re … Orin Dafidi 139:14 Emi ni mo ran gbogbo isan re papo nigbati o wa l’oyun … Orin Dafidi 139:13 Emi ni mo mu o jade kuro ninu oyun lojo ibi re … Orin Dafidi 71:6 Opolopo ti ko mo mi ni won ti ba mi je l’oju aye …Johannu 8:41 Emi ko jina; beeni nko si binu. Pipe ni ife mi …1 Johannu 4:16 Emi si nfe fi opolopo ife ba o lo …1 Johannu 3:1 Eleyi ribe nitoriwipe omo mi ni iwo i se; Emi si ni Baba re …1 Johannu 3:1 Ebun ti Mo nfun o po ju iye ti baba re ninu aye yi le fun o lo …Matteu 7:11 Emi ni Baba t’O pe …Matteu 5:48 Gbogbo ebun pipe ti onri gba, lati owo mi ni o ti wa …Jakobu 1:17 Emi ni Olupese re ti yoo ba aini re pade l’otito …Matteu 6:31-33 Eto mi fun o ni lati fun o ni ireti …Jeremiah 29:11 Eleyi ri bee; nitori mo feran re pelu ife ayeraye …Jeremiah 31:3 Ironu mi si o ju ti iyanrin eti okun lo ... Orin Dafidi 139:17-18 Emi a si maa yo lori re pelu orin kiko …Sefania 3:17 Emi ki yo dawoduro lati maa se rere si o …Jeremiah 32:40 Iwo ni eso mi …Eksodu 19:5 Emi nfe lati fi ese re mule pelu gbogbo okan ati aya mi …Jeremiah 32:41 Mo si fe fi nkan iyanu han o …Jeremiah 33:3 Ti o ba fi gbogbo okan re wa mi, iwo yoo ri mi …Deuteronomy 4:29 Fi gbogbo okan re fe mi, Emi yoo si fun o ni ohun ti o nfe … Orin Dafidi 37:4 Nitoriwipe Emi ni O sise ife ati ise sise ninu re …Filippi 2:13 Emi le se ju nkan ti o l’ero re lo …Efesu 3:20 Emi ni Eniti o le ti o l’ehin julo …2 Tesalonika 2:16-17 Emi si ni Baba ti O ntu o ninu …2 Korinti 1:3-4 Nigbati okan re ba baje, mo wa pelu re …Orin Dafidi 34:8 Gegebi olusaguntan se ngbe awon agutan re ni mo ngbe o mo’ra ...Isaiah 40:11 Ojo nbo wa ti Emi yoo nu gbogbo omije re nu kuro …Ifihan 21:3-4 Emi yoo si mu gbogbo irora ti o ti ni ninu ile aye yi kuro …Ifihan 21:3-4 Emi ni Baba re; ife kanna ti mo ni fun Jesu ni mo ni fun o …Johannu 17:23 Ninu Jesu ni a ti fi ife mi han …Johannu 17:26 Oun ni Alasepe ifihan bi mo se je ni gboogi …Heberu 1:3 O wa lati fi han gbangba wipe Emi wa fun o; Emi ki I se alatako re …Romu 8:31 Ati lati so fun o wipe Emi ki I ka ese si o l’orun …2 Korinti 5:18-19 Jesu ku lati se ise ilaja larin iwo ati Emi …2 Korinti 5:18 Iku Re je alasepe ifihan ife mi si o …1 Johannu 4:10 Mo fi ohun gbogbo sile lati ri ife re …Romu 8:31,32 Ti o ba gba ebun ife ti Jesu, Omo mi, o fihan wipe o ti gba mi niyen …1 Johannu 2:23 Ko si si ohun kan ti o le ya iwo ati fe mi nipa. …Romu 8:38,39 Pada wa s’ile ki ajoyo ti o larinrin le bere ni ajule orun …Luku 15:7 Baba ni mo je; titi ayeraye, Baba na a si ni Emi yoo ma a je …Ephesians 3:14-15 Ibeere ti mo ni fun o ni wipe , nje iwo ha setan lati di omo mi? …Johannu 1:12-13 Nje, Mo nduro de o o …Luku 15:11-32 Ife mi wa fun o, Emi ni Baba re, Olorun Olodumare Father’s Love Letter used by permission Father Heart Communications Copyright 1999-2004 Yoruba translation by Kayode Sojobe www.FathersLoveLetter.com/Yoruba

Upload: others

Post on 25-Jan-2020

6 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

Page 1: Leta Ife Lati Odo Olorun Baba - The Lord Loves You · 2010-04-09 · Leta Ife Lati Odo Olorun Baba Iwo, Omo mi owon,… O le ma mo mi; sugbon, mo mo ohun gbogbo nipa re …Orin Dafidi

Leta Ife Lati Odo Olorun Baba

Iwo, Omo mi owon,…

O le ma mo mi; sugbon, mo mo ohun gbogbo nipa re …Orin Dafidi 139:1 Emi mo gbogbo bi o se njoko ti o si ndide … Orin Dafidi 139:2 Ko si ohun kan nipa re ti o s’okunkun si mi … Orin Dafidi 139:3 Emi mo iye irun ti o wa l’ori re …Matteu 10:29-31 Ni aworan ara mi ni a da o …Genesisi 1:27 Ninu mi ni o ngbe, ni o nrin, ti o si nni iye …Ise Awon Aposteli 17:28 Lati inu mi ni o ti jade wa …Ise Awon Apostei 17:28 Ki a to bi o ni mo ti mo o…Jeremiah 1:4-5 Mo ti yan o ni ayo ki nto da ohun gbogbo…Efesu 1:11-12 Igbesi aye re ko le je asise; nitori wipe mo ti ko won si inu iwe mi …Orin Dafidi 139:15-16 Emi ni mo se ipinnu asiko gere eyi ti a bi o ati ibiti o ma a ma gbe …Ise Awon Aposteli 17:26 Iyanu gan ni eda re … Orin Dafidi 139:14 Emi ni mo ran gbogbo isan re papo nigbati o wa l’oyun … Orin Dafidi 139:13 Emi ni mo mu o jade kuro ninu oyun lojo ibi re … Orin Dafidi 71:6 Opolopo ti ko mo mi ni won ti ba mi je l’oju aye …Johannu 8:41 Emi ko jina; beeni nko si binu. Pipe ni ife mi …1 Johannu 4:16 Emi si nfe fi opolopo ife ba o lo …1 Johannu 3:1 Eleyi ribe nitoriwipe omo mi ni iwo i se; Emi si ni Baba re …1 Johannu 3:1 Ebun ti Mo nfun o po ju iye ti baba re ninu aye yi le fun o lo …Matteu 7:11 Emi ni Baba t’O pe …Matteu 5:48 Gbogbo ebun pipe ti onri gba, lati owo mi ni o ti wa …Jakobu 1:17 Emi ni Olupese re ti yoo ba aini re pade l’otito …Matteu 6:31-33 Eto mi fun o ni lati fun o ni ireti …Jeremiah 29:11 Eleyi ri bee; nitori mo feran re pelu ife ayeraye …Jeremiah 31:3 Ironu mi si o ju ti iyanrin eti okun lo ... Orin Dafidi 139:17-18 Emi a si maa yo lori re pelu orin kiko …Sefania 3:17 Emi ki yo dawoduro lati maa se rere si o …Jeremiah 32:40 Iwo ni eso mi …Eksodu 19:5 Emi nfe lati fi ese re mule pelu gbogbo okan ati aya mi …Jeremiah 32:41 Mo si fe fi nkan iyanu han o …Jeremiah 33:3 Ti o ba fi gbogbo okan re wa mi, iwo yoo ri mi …Deuteronomy 4:29 Fi gbogbo okan re fe mi, Emi yoo si fun o ni ohun ti o nfe … Orin Dafidi 37:4 Nitoriwipe Emi ni O sise ife ati ise sise ninu re …Filippi 2:13 Emi le se ju nkan ti o l’ero re lo …Efesu 3:20 Emi ni Eniti o le ti o l’ehin julo …2 Tesalonika 2:16-17 Emi si ni Baba ti O ntu o ninu …2 Korinti 1:3-4 Nigbati okan re ba baje, mo wa pelu re …Orin Dafidi 34:8 Gegebi olusaguntan se ngbe awon agutan re ni mo ngbe o mo’ra ...Isaiah 40:11 Ojo nbo wa ti Emi yoo nu gbogbo omije re nu kuro …Ifihan 21:3-4 Emi yoo si mu gbogbo irora ti o ti ni ninu ile aye yi kuro …Ifihan 21:3-4 Emi ni Baba re; ife kanna ti mo ni fun Jesu ni mo ni fun o …Johannu 17:23 Ninu Jesu ni a ti fi ife mi han …Johannu 17:26 Oun ni Alasepe ifihan bi mo se je ni gboogi …Heberu 1:3 O wa lati fi han gbangba wipe Emi wa fun o; Emi ki I se alatako re …Romu 8:31 Ati lati so fun o wipe Emi ki I ka ese si o l’orun …2 Korinti 5:18-19 Jesu ku lati se ise ilaja larin iwo ati Emi …2 Korinti 5:18 Iku Re je alasepe ifihan ife mi si o …1 Johannu 4:10 Mo fi ohun gbogbo sile lati ri ife re …Romu 8:31,32 Ti o ba gba ebun ife ti Jesu, Omo mi, o fihan wipe o ti gba mi niyen …1 Johannu 2:23 Ko si si ohun kan ti o le ya iwo ati fe mi nipa. …Romu 8:38,39 Pada wa s’ile ki ajoyo ti o larinrin le bere ni ajule orun …Luku 15:7 Baba ni mo je; titi ayeraye, Baba na a si ni Emi yoo ma a je …Ephesians 3:14-15 Ibeere ti mo ni fun o ni wipe , nje iwo ha setan lati di omo mi? …Johannu 1:12-13 Nje, Mo nduro de o o …Luku 15:11-32

Ife mi wa fun o, Emi ni Baba re, Olorun Olodumare

Father’s Love Letter used by permission Father Heart Communications Copyright 1999-2004 Yoruba translation by Kayode Sojobe

www.FathersLoveLetter.com/Yoruba