iwadi nipa eniyan ati ilera won ni odun 2013 2013 nigeria ...iwadi nipa eniyan ati ilera won ni odun...
TRANSCRIPT
Iwadi Nipa Eniyan Ati Ilera Won Ni Odun 20132013 Nigeria Demographic and Health Survey
Ibisi
Okookan ninu awon obinrin ile Naijiria ni omo marun ati aabo (5.5). Ibisi ni ila iwo oorun Afirika wa laarin omo merin ni orile ede Ghana si mejo ni orile ede Niger.
Ilera abiyamoBii ibimo merin ninu mewa ni o ni
iranlowo osise eto ilera.
Ifeto somo bibi
Ida meedogun ninu ogorun pere lo lo eyikeyi ninu eto ilana ifeto
somo bibi. Lilo ilana fifi eto somo bibi wa laarin ida meta ninu
ogorun ni ila oorun ariwa si ida mejidinlogbon ni iwo oorun gusu.
Gbigba abere ajesara
Gbigba abere ajesara ti gberu si ni ile Naijiria. Okan ninu omo merin ti o je osu mejila si metalelogun ni o gba gbogbo abere ajesara.
© Abt Associates Nigeria/PATHS2 Project
Apapo ibisi ni awon orile ede iwo oorun Afirika
Ibisi fun obinrin kan laarin odun meta siwaju iwadi naa
Ghana2008 DHS
5.04.0
5.04.9
Benin2011-12
DHS
Cote d’Ivoire2011-12
DHS
Senegal2010-11
DHS
Sierra Leone2008DHS
Liberia2007DHS
Nigeria2013DHS
Burkina Faso2010DHS
Mali2006DHS
Niger2012DHS
5.1 5.2 5.5 6.0 6.67.6
Bi lilo ilana ifeto somo bibi se gbile si ni elekunjekun
Nigeria15%
Ida ninu ogorun awon obinrin ti o wa ni ile oko lowolowo ti ojo ori won wa laarin odun meedogun si mokandinlaadota
ti won n lo eyikeyi ninu ilana ifeto somo bibi
10-25% >25% <10%
North East3%
North West4%
North Central16%
South West38%
South East29%
South South28%
BCG DPT 3 Polio 3
Bi eto abere ajesara se n lo si
48
2003 NDHS 2008 NDHS 2013 NDHS
5150
21
383529
5439
Ida lona ogorun awon omode ti o je osu mejila si metalelogun ti o gba abere ajesara
Measles All None
364241
132523 27
2129
Iku omode
Isiro se afihan wiwa sile gbogbo ipele iku omode lati odun 2003.
Bi iku omode se n lo siIda lona egberun iku lori awon omo ti a bi laaye
2008 NDHS
Iku omo ti ko pe odun kan
75 69
128
Iku omo ti ko pe odun marun
2013 NDHS
157
201
100
2003 NDHS
Iku omo ti ko pe osu kan
40 3748
NAIJIRIA
Iranlowo lasiko ibimo
*Ida mejidinlogoji ibimo ni o ni
iranlowo osise eto ilera.
Onise ilera agbegbe2%
Oluranlowo noosi/agbebi3%
Dokita10%
Noosi/agbebi25%
Agbebi ibile22%
Ibatan/elomiran23%
Ko si enikankan
13%
Don’t know1%
*Osise eto ilera je dokita, noosi, agbebi, ati oluranlowo noosi/agbebi.
© 2
012
Aki
ntun
de A
kinl
eye-
NU
HRI
, Cou
rtes
y of
Pho
tosh
are