edidi olorun alayeokon[emi] ati iwa orun omo re olufe owon niti etutu fun ese awon ese araye ati...

1
E D I D I O L O R U N A L A Y E Gba adura yi lojoojumo Gbogbo eniti oba gba Edidi yi ni a o fi aabo fun, enikokan ati awon ebi re ni akoko ipadabo Kristi Lekeji Ti afifun mi, ni February 20, 2012 Adura Pataki yi ni ebun ti afifun ni lati Odo olorun Baba wa nipase wolli Maria Divine Mercy fun aabo Gbogbo awon omo olorun . Edidi Olorun Alaye Dide nisinsinyi ki osi gba Edidi mi, Edidi Olorun Alaye. Ka adura isoji yi(33) lati jewo ati lati gbaa pelu Ife, Ayo ati Idupe. Olorun mi, Baba mi Olufe, mo gba Edidi aabo re atoke wa pelu ife ati idupe. Iwa Orun Re yi ara ati emi mi ka fun ayeraye. Mo teriba pelu owo, idupe, ati okan ati iwa isooto mi fun Baba mi Olufe. Mo be O pe ki o pami mo ati awon ololufe ni pelu Edidi Pataki, mo yonda aye mi ilo Re lai ati titi lailai. Mo feran Baba mi owon, mo be o Baba mi owon ni akoko bi iru eyi. Mo fi ara, eje, okon[emi] ati iwa orun omo Re Olufe owon niti etutu fun ese awon ese araye ati igbala awon omo Re. Amin Lo, eyin omo ki ema si se beru. Gbekele mi, Baba re Ololufe. Eniti oda gbogbo yin ninu ife. Mo mo okan kookan gbogbo ago re ni mom o. Ko si eniti ife mi keresi julo. Nitori eyi mi o fe so okan Kankan nu Kii tile se enikan. Jowo ma gbadura fun ile yosin Divine Mercy lojoojumo. Lojokan, oye yo ye o eredi ti afi nilo iwenu mo. Baba Olufe ti nbe Lorun Olorun to Ga Julo

Upload: others

Post on 23-Mar-2020

5 views

Category:

Documents


5 download

TRANSCRIPT

Page 1: Edidi Olorun Alayeokon[emi] ati iwa orun omo Re Olufe owon niti etutu fun ese awon ese araye ati igbala awon omo Re. Amin Lo, eyin omo ki ema si se beru. Gbekele mi, Baba re Ololufe

ED

IDI O L O R U N AL

AY

E

Gba adura yi lojoojumo Gbogbo eniti oba

gba Edidi yi ni a o fi aabo fun,

enikokan ati awon ebi re ni akoko

ipadabo Kristi Lekeji

Ti afifun mi, ni February 20, 2012

Adura Pataki yi ni ebun ti afifun ni lati

Odo olorun Baba wa nipase wolli

Maria Divine Mercy fun aabo Gbogbo

awon omo olorun

.

Edidi Olorun Alaye

Dide nisinsinyi ki osi gba Edidi mi, Edidi Olorun Alaye.

Ka adura isoji yi(33) lati jewo ati lati gbaa pelu Ife, Ayo ati Idupe. Olorun mi, Baba mi Olufe, mo gba Edidi aabo re atoke wa pelu ife ati idupe. Iwa Orun Re yi ara ati emi mi

ka fun ayeraye. Mo teriba pelu owo, idupe, ati okan ati iwa isooto mi fun Baba mi Olufe. Mo be O pe ki o pami mo ati awon ololufe ni pelu Edidi Pataki, mo yonda aye mi ilo Re lai ati titi lailai. Mo feran Baba mi owon, mo be o Baba mi owon ni akoko bi iru eyi. Mo fi ara, eje, okon[emi] ati iwa orun omo Re Olufe owon niti etutu fun ese awon ese araye ati igbala awon omo Re. Amin

Lo, eyin omo ki ema si se beru. Gbekele mi, Baba re Ololufe. Eniti oda gbogbo yin ninu ife. Mo mo okan kookan gbogbo ago re ni mom o. Ko si eniti ife mi keresi julo. Nitori eyi mi o fe so okan Kankan nu Kii tile se enikan.

Jowo ma gbadura fun ile yosin Divine Mercy lojoojumo. Lojokan, oye yo ye o eredi ti afi nilo iwenu mo.

Baba Olufe ti nbe Lorun

Olorun to Ga Julo