2008 nigeria demographic and health survey (ndhs): nigeria demographic and health survey (ndhs ......

Download 2008 Nigeria Demographic and Health Survey (NDHS): Nigeria Demographic and Health Survey (NDHS ... 2008 Nigeria Demographic and Health Survey ... Awon ebi ti o ni okere ju apo efon

Post on 01-Mar-2018

237 views

Category:

Documents

10 download

Embed Size (px)

TRANSCRIPT

 • 2008 Nigeria Demographic and Health Survey (NDHS): South West

  Nigeria 5.7

  South West4.5

  Odiwon gbogbo ibisi ni ipinle kookanIye omo ti obinrin kookan bi

  Ekiti5.0

  Lagos4.0

  Ogun5.4

  Ondo4.9

  Osun4.0

  Oyo5.0

  54

  80 8490

  6875 78 70

  Nigeria SouthWest

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  Mooko mooka: Awon obinrinIda lona ogorun awon obinrin ti ojo ori won je

  meedogun si o kan din ladota ti won mooko mooka

  7790 92 96

  76 8093

  85

  Nigeria SouthWest

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  Mooko mooka: Awon okunrinIda lona ogorun awon okunrin ti ojo ori won je

  meedogun si o kan din ladota ti won mooko mooka

  10

  2115

  28

  13 15

  27

  18

  Nigeria SouthWest

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  Lilo ona Ifeto somo bibiIda lona ogorun awon ti o loko lowolowo ti ojo ori won si je odun meedogun si mokan din laadota ti

  won n lo ona igbalode lati fi feto somo bibi

  23

  43

  58 53

  2337

  59

  31

  Nigeria SouthWest

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  Bi abere ajesara se gbile siIda lona ogorun omowewe ti ojo ori won je osu mejila si osu metalelogun ti o ti gba gbogbo abere ajesara ti o ye

  * Gba gbogbo abere ajesara pelu abere ti o n dena iko fee (BCG), ita (measles) ati iwon meta abere DPT ati abere fun idena arun romo lowo romo lese (Polio).

  Ekiti33%

  Lagos21%

  Ogun42%

  Ondo32%

  Osun31%

  Oyo37%

  Nigeria41%

  South West31%

  Kikuru ni ipinle kookanIda lona ogorun awon omo ti ojo ori re kere ju odun marun ti won ko si ga to (ti o kuru ju fun ojo ori re)

  58

  87 93 88 90

  70

  94 88

  39

  77 8183

  72

  51

  8976

  Nigeria SouthWest

  Gba itoju oyun lati owo awon ti o ni imo to peye nipa itoju oyun

  Gba itoju lati owo awon ti o ni imo to peye nipa ibimo

  Itoju abiyamoIda lona ogorun awon obinrin ti o bi abiye

  ni bii odun marun ki ato se iwadi yi

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  * Awon ti o ni imo to peye pelu dokita, noosi/agbebi, tabi awon ti oun ran agbebi lowo/agbebi.

  23 2718

  27 2720

  3725

  36 3742 38 40

  33

  58

  19

  Nigeria SouthWest

  Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  Imo ti o peye lori bi ati le yago fun kiko arun ti ko gboogun (HIV)

  Ida lona ogorun awon ti ojo ori won je meedogun si o kan din ladota ti osi ni imo ti o peye lori aisan ti ko gboogun HIV ati AIDS

  Awon obinrin Awon okunrin

  * Imo ti o peye tumo si mimo wipe ki a maa lo roba idabobo ni igba ibalopo ati pe ki a ni oni balopo ti ko ko arun ti osi je olotito kan le din ewu ki ko arun ti ko gboogun (HIV) ku, ni iwon ti amo wipe eniyon ti oju re dan gbinrin le ni aisan HIV, ati kiko ona meji ti o wopo nipa ero ti awon eniyan ni lori bi aisa ti ko gboogun (HIV) gbile ati bi ati le yaago fun.

  Iwadi nipa awon eniyan ati ilera won ni lle Nigeria ti ase ni odun 2008 pese iroyin ti o peye nipa awon eniyan ati ilera won ni ile Nigeria. Iwadi yi je ekerin kokari iwadi nipa awon eniyan ati ilera won ti ati se ni orile ede yi.

  Iwadi na wa lori awon ti a sha lati soju awon eniyon orile ede Nigeria. O fun wa ni bi nkan se ri ni igberiko ati awon ilu nla ni orile ede Nigeria, elekunjekun kookan, ati, ni opolopo igba, ni ipinle kookan ninu merindinlogoji ti owa,ati olu ilu ile Nigeria (FCT)

  NumberBi won se

  daun si

  Awon ebi ti ase iwadi lowore 34,070 98%

  Awon obinrin ti ojo ori won je meedogun si o kan din ladota ti ase iwadi lowore

  33,385 97%

  Awon okunrin ti ojo ori won je meedogun si o kan din logota ti ase iwadi lowore

  15,486 93%

 • 2008 Nigeria Demographic and Health Survey

  Fact Sheet

  Fun imonran si lori agejade iwadi nipa eniyan ati ilera won ti ase ni odun 2008, e elo si:

  Ni Nigeria:National Population CommissionPlot 2031, Olusegum Obasanjo Way, Zone 7 Wuse, PMB 0281Abuja, NigeriaTelephone: (234) 09 523-9173Fax: (234) 09 523-1024Website: www.population.gov.ng

  Ni Amerika:MEASURE DHS, ICF Macro11785 Beltsville DriveCalverton, MD 20705 USATelephone: 301-572-0200Fax: 301-572-0999Website: www.measuredhs.com

  Ile ise eto ikaniyan ti ile Nigeria (National popu-lation commission) ni o se iwadi 2008 NDHS. Ile ise ICF Macro, ti ise ile ise kokari awon orile ede (ICF International Company) ni o se iranlowo imo ijinle iwadi naa, igbekale iwadi ati lati gbe esi iwadi na yewo lona eto isuna ti ajo USAID-la sile fun MEASURE DHS. Ipese owo fun iwadi naa wa lati odo ajo USAID ati owo pajawiri ti Aare pese fun idojuko aarun AIDS (Presidents Emergency Fund for AIDS Relief)-PEPFAR. Ajo ile ise United Nations Population Fund (UNFPA) ni o se inawo bi atile mo ibi ti atile se iwadi yi ati lati mo ebi ti a o se iwadi lowo re.

  Ekiti63%

  Lagos63%

  Ogun66%

  Ondo63%

  Osun76%

  Oyo71%

  Omi ti awon ebi n mu ni ipinle kookanIda lona ogorun awon ebi ti oni ibi ti

  won ti n pon omimimu ti odara

  Nigeria56%

  South West67%

  Ekiti17%

  Lagos24%

  Ogun13%

  Ondo15%

  Osun13%

  Oyo7%

  Nigeria27%

  South West16%

  O hun elo ifintoto ti awon ti ebi ni ni ipinle kookanIda lona ogorun awon ebi ti oni ibi ti odara, ti a ko si pin lo

  Ekiti63%

  Lagos91%

  Ogun66%

  Ondo48%

  Osun67%

  Oyo62%

  Nigeria50%

  South West71%

  Ebi ti o ni ina monamona ni ipinle kookanIda lona ogorun ebi ti o ni ina monamona

  South West ZoneYoruba

 • State

  Nigeria

  South West Zone Ekiti Lagos Ogun Ondo Osun Oyo

  IbisiOdiwon gbogbo ibisi ni elekunjekun 5.7 4.5 5.0 4.0 5.4 4.9 4.0 5.0

  Awon obinrin ti ojo ori won je odun meedogun si mokandinlogun ti won je abiyamo tabi loyun bayi (%)

  23 9 8 5 12 8 5 20

  Ibimo ti ko tii to odun meji lehin ibimo ti o siwaju re (%) 24 16 17 18 18 16 11 15

  Ifeto somo bibi

  Lilo ona igbalode bayi (awon ti o loko lowolowo ti ojo ori re si je odun meedogun si mokan din laadota) (%)

  10 21 15 28 13 15 27 18

  Ilera Iya ati omoItoju lati ile igbebi

  Awon obinrin ti o bimo ti o si gba itoju oyun lati owo awon ti o ni imo to peye nipa itoju oyun1 (%)

  58 87 93 88 90 70 94 88

  Ibimo pelu iranlowo lati owo awon ti o ni imo to peye nipa ibimo1 (%)

  39 77 81 83 72 51 89 76

  Awon omo ti a bi ni ile iwosan (%) 35 70 75 77 64 47 85 67

  Abere ajesara fun omode

  Omowewe ti ojo ori won je osu mejila si osu metalelogun ti o ti gba gbogbo abere ajesara ti o ye2 (%)

  23 43 58 53 23 37 59 31

  Omowewe ti ojo ori won je osu mejila si osu metalelogun ti ko gba abere ajesara kankan (%)

  29 13 2 12 27 23 5 9

  Eto o njeAwon omo ti ojo ori re kere ju odun marun ti won ko si ga to (ti o ga niwonba tabi ko ga rara) (%)

  41 31 33 21 42 32 31 37

  Awon omo ti ojo ori won kere ju odun marun ti won ko lara (ti won lara niwonba tabi o gbe ju) (%)

  14 9 5 10 7 6 12 12

  Awon omo ti ojo ori won kere ju odun marun ti iwon won kere (ti o won niwonba tabi iwon won kere ju) (%)

  23 13 9 10 18 11 13 17

  Aisan Iba

  Awon ebi ti o ni okere ju apo efon ITN kan eyi ti ati re pelu oogun apefon (%)

  8 6 12 9 5 5 2 2

  Awon omo ti o kere ju odun marun ti won sun si abe apo efon ITN moju ojo ti ase iwadi yi (%)

  6 5 13 7 5 4 2 2

  Awon aboyun ti o sun si abe apo efon ITN moju ojo ti ase iwadi yi (ida lona ogorun) (%)

  5 3 5 2 10 1 0 4

  Umunwanyi di ime ndi natara ogwu SP/Fansidar uzo ugboro abua ndi ka IPT oge ha gara nlezianya umunwanyi di ime (%)

  5 6 5 6 6 5 5 8

  Imo nipa aarun ti ko gboogun (HIV/AIDS)

  Mo wipe ale din ewu ati ko arun tiko gboogun (HIV) ku ni pa:Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Nini onibalopo kan soso (%) 68/83 67/82 65/70 66/78 74/85 55/81 85/94 60/85

  Lilo roba idabobo (%) 53/72 59/73 63/74 54/65 63/80 53/70 80/87 53/77

  Mo wipe o seese ki eni ti oju re ndan gbirin ni arun ti ko gboogun (HIV) (%)

  66/78 78/86 80/85 87/92 64/88 66/71 88/90 68/76

  Mo wip omo kekere le ko aarun tiko gboogun (HIV) nipa mimu oyan (%)

  52/59 67/59 45/64 72/60 63/56 64/70 71/41 66/63

  Mo wipe ale din ewu tio wa ninu MTCT ku nipa wipe ki iya lo oogun oto nigba iloyun (%)

  28/39 28/34 21/24 48/46 15/21 17/15 11/24 23/39

  Bi ile seriEbi ti oni ibi ti won ti n pon omimimu ti odara (%) 56 67 63 63 66 63 76 71

  Ebi ti oni ina monamona (%) 50 71 63 91 66 48 67 62

  Ebi ti oni ile igbonse ti odara (%) 27 16 17 24 13 15 13 7

  Eko Obinrin/OkunriObinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Obinrin/Okunri

  Mooko mooka (%) 54/77 80/90 84/92 90/96 68/76 75/80 78/93 70/85

  Ko ni eko (%) 36/19 12/5 8/2 6/3 19/10 14/5 13/3 20/11

  1 Awon ti o ni imo to peye pelu dokita, noosi/agbebi, tabi awon ti oun ran agbebi lowo/agbebi. 2 Gba gbogbo abere ajesara pelu abere ti o n dena iko fee (BCG), ita (measles) ati iwon meta abere DPT ati abere fun idena arun romo lowo romo lese (Polio)

  South West Zone

  South West fact sheet (Yoruba)South West indicator table (Yoruba)

Recommended

View more >